AI nínú àpótí ìdìbò: Ìgbésẹ̀ mẹ́ rin láti dá ààbò bo ètò ìdìbò àti mú ìṣèjọba àwaarawa dúró ire
| dc.contributor.author | Régis, Catherine | |
| dc.contributor.author | Martin-Bariteau, Florian | |
| dc.contributor.author | Effoduh, Jake Okechukwu | |
| dc.contributor.author | Gutiérrez, Juan David | |
| dc.contributor.author | Neff, Gina | |
| dc.contributor.author | Souza, Carlos Affonso | |
| dc.contributor.author | Zolynski, Célia | |
| dc.date.accessioned | 2025-07-03T13:47:49Z | |
| dc.date.available | 2025-07-03T13:47:49Z | |
| dc.date.issued | 2025-02-01 | |
| dc.description.abstract | Àwọn àpẹẹrẹ láti Brazil, Romania, Gabon àti United States àtàwọn orílẹ̀ èdè míì ti ṣàfihàn báwọn olóṣèlú ṣe lè lo AI láti dójú ètò ìdìbò àti ìjọba àwaarawa bolẹ̀ . Ọ̀ pọ̀ àwọn orílẹ̀ èdè ni kìí gbáradì fáwọn ìpèníjà tó lè tara AI jáde: ọ̀ pọ̀ àwọn orílẹ̀ èdè ni kò ní òfin tó de AI lílò lásìkò ètò ìdìbò, àwọn ẹgbẹ́ ṣẹ̀ ṣẹ̀ wáyé láti Brazil, Romania, Gabon, òṣèlú kò ì tíì fẹnukò lórí ìlànà ètò ìdìbò tó yẹ lásìkò ayé AI yìí àti ọ̀ pọ̀ ni kò ní ìkápá láti kojú àwọn ìpèníjà tì AI ní lórí ètò ìṣèjọba àwaarawa. Àwọn ìgbésẹ̀ mẹ́ rin ni a rò pé ó yẹ láti gbé: ìjọba nílò láti ṣàtúnṣe àwọn òfin ètò ìdìbò (fún àpẹẹrẹ láti fòfin de lílo AI láti ṣe àwọn nǹkan tó lè ṣi ará ìlú lọ́ kàn); àwọn ẹgbẹ́ òṣèlú gbọdọ̀ ní ìlànà ìhùwàsí lórí lílo AI fọ́ rọ̀ òṣèlú; àwọn aláṣẹ ètò ìdìbò ní láti gbé ikọ̀ kan dìde. | |
| dc.description.sponsorship | Àkànṣe iṣẹ ́ yìí jẹ ́ ṣíṣe, ọpẹ ́ pàtàkì sí ìdásí Fonds de recherche du Québec, CEIMIA, alága Canada CIFAR lẹ ́ ka AI and Human Rights ní Mila àti alága ẹ ̀ ka ìwádìí nípa ìmọ̀ ẹ ̀ rọ àti àwùjọ ní ilé ẹ ̀ kọ́ gíga University of Ottawa, àti ìrànlọ́ wọ́ ikọ̀ Délégation du Québec à Rome àti SIOI fún ṣíṣe àgbákalẹ ̀ ìpàdé náà. | |
| dc.identifier.uri | http://hdl.handle.net/10393/50608 | |
| dc.language.iso | Yorùbá | |
| dc.rights | Attribution-NonCommercial-NoDerivatives 4.0 International | en |
| dc.rights.uri | http://creativecommons.org/licenses/by-nc-nd/4.0/ | |
| dc.subject | Democracy | |
| dc.subject | Elections | |
| dc.subject | Artificial intelligence | |
| dc.title | AI nínú àpótí ìdìbò: Ìgbésẹ̀ mẹ́ rin láti dá ààbò bo ètò ìdìbò àti mú ìṣèjọba àwaarawa dúró ire | |
| dc.type | Report |
