AI nínú àpótí ìdìbò: Ìgbésẹ̀ mẹ́ rin láti dá ààbò bo ètò ìdìbò àti mú ìṣèjọba àwaarawa dúró ire

En cours de chargement...
Vignette d'image

Nom de la revue

ISSN de la revue

Titre du volume

Éditeur

Licence Creative Commons

Attribution-NonCommercial-NoDerivatives 4.0 International

Résumé

Àwọn àpẹẹrẹ láti Brazil, Romania, Gabon àti United States àtàwọn orílẹ̀ èdè míì ti ṣàfihàn báwọn olóṣèlú ṣe lè lo AI láti dójú ètò ìdìbò àti ìjọba àwaarawa bolẹ̀ . Ọ̀ pọ̀ àwọn orílẹ̀ èdè ni kìí gbáradì fáwọn ìpèníjà tó lè tara AI jáde: ọ̀ pọ̀ àwọn orílẹ̀ èdè ni kò ní òfin tó de AI lílò lásìkò ètò ìdìbò, àwọn ẹgbẹ́ ṣẹ̀ ṣẹ̀ wáyé láti Brazil, Romania, Gabon, òṣèlú kò ì tíì fẹnukò lórí ìlànà ètò ìdìbò tó yẹ lásìkò ayé AI yìí àti ọ̀ pọ̀ ni kò ní ìkápá láti kojú àwọn ìpèníjà tì AI ní lórí ètò ìṣèjọba àwaarawa. Àwọn ìgbésẹ̀ mẹ́ rin ni a rò pé ó yẹ láti gbé: ìjọba nílò láti ṣàtúnṣe àwọn òfin ètò ìdìbò (fún àpẹẹrẹ láti fòfin de lílo AI láti ṣe àwọn nǹkan tó lè ṣi ará ìlú lọ́ kàn); àwọn ẹgbẹ́ òṣèlú gbọdọ̀ ní ìlànà ìhùwàsí lórí lílo AI fọ́ rọ̀ òṣèlú; àwọn aláṣẹ ètò ìdìbò ní láti gbé ikọ̀ kan dìde. This is a translation in Yoruba of a document initially published in English: https://doi.org/10.20381/ruor-31187

Description

Mots-clés

Democracy, Elections, Artificial intelligence

Citation

Approbation

Évaluation

Complété par

Référencé par