Ṣíṣe ìjọba pẹ̀ lú AI : Àwọn ìgbésẹ̀ mẹ́ rin láti mú àyípadà ọ̀ tún àti ṣíṣe àkóso ìṣèjọba tó dúró ire

dc.contributor.authorRégis, Catherine
dc.contributor.authorMartin-Bariteau, Florian
dc.contributor.authorAdams, Rachel
dc.contributor.authorBertrand, Brunessen
dc.contributor.authorEffoduh, Jake Okechukwu
dc.contributor.authorParycek, Peter
dc.contributor.authorPereira de Souza, Carlos Affonso
dc.contributor.authorYoon, Hyesun Melissa
dc.date.accessioned2026-06-01T16:04:19Z
dc.date.available2026-06-01T16:04:19Z
dc.date.issued2026-05-26
dc.description.abstractAI kìí ṣe ọ̀ nà àbùjá láti ṣe àtúntò ìjọba. Láì sí àlàkalẹ̀ ìlànà ìṣàmúlò fún àtúntò, ohun èlò tó pójú owó àti ìlànà ìṣèjọba tó yé yéké, ṣíṣe àmúlò AI, ó ṣeé ṣe kí ìṣàmúlò rẹ̀ mú ìkúrẹtẹ̀ bá ètò ìṣejọba àti àìsí ìbòjútó pọ̀ si ju kí ó mú ìgbéga bá tàbí ṣíṣe tàbí òdodo lọ Àṣeyọrí AI nínú ìjọba jẹ́ ìpèníjà fún ìṣèjọba kìí ṣe ti ìmọ̀ ẹ̀ rọ. Àwọn àbájáde kò gbáralé bí ìmọ̀ ẹ̀ rọ ṣe lágbára tó dípò bí àwọn ilé iṣẹ́ ṣe lágbára sí, àwọn ìlànà ìṣàfihàn, agbára àjọṣepọ̀ àwọn olùtajà, àti ìlànà ìfaradà. A ṣe àgbékalẹ̀ ìgbésẹ̀ mẹ́ rin: ṣíṣe àtúntò àwọn ohun tí aráàlú ń lò lórí àwọn ìṣòro rẹ̀ gangan ṣáájú ṣíṣe àgbákalẹ̀ AI; ṣíṣe ìdókoòwò sí ṣíṣe ìdánilẹ́ kọ̀ ọ́ fáwọn òṣìṣẹ́ ní gbogbo ẹ̀ ka, ṣàgbéyẹ̀ wò agbára àwọn olùtajà láti ri pé àjọṣepọ̀ wà nípasẹ̀ ríra ọjà lápapọ̀ àti ìlò AI èyí tí aráàlú jẹ́ aṣojú rẹ̀ lábẹ́ àkóso kan èyí tí wọ́ n gbé kalẹ̀ lórí ìṣàfihàn tòótọ́ àti àbójútó tó péye. * Original document in English: https://doi.org/10.20381/s959-yx05
dc.identifier.doihttps://doi.org/10.20381/1npf-nh06
dc.identifier.urihttp://hdl.handle.net/10393/51723
dc.identifier.urihttps://doi.org/10.20381/1npf-nh06
dc.language.isoother
dc.rightsAttribution-NonCommercial-NoDerivatives 4.0 Internationalen
dc.rights.urihttp://creativecommons.org/licenses/by-nc-nd/4.0/
dc.subjectartificial intelligence
dc.subjectgovernment
dc.subjectpublic sector
dc.titleṢíṣe ìjọba pẹ̀ lú AI : Àwọn ìgbésẹ̀ mẹ́ rin láti mú àyípadà ọ̀ tún àti ṣíṣe àkóso ìṣèjọba tó dúró ire

Fichiers

Trousse originale

Voici les éléments 1 - 1 sur 1
En cours de chargement...
Vignette d'image
Nom:
GPB-IA_Gov_Yoruba_DOI.pdf
Taille:
438.41 KB
Format:
Adobe Portable Document Format

Trousse de licence

Voici les éléments 1 - 1 sur 1
En cours de chargement...
Vignette d'image
Nom:
license.txt
Taille:
2.51 KB
Format:
Item-specific license agreed upon to submission
Description: