Ṣíṣe ìjọba pẹ̀ lú AI : Àwọn ìgbésẹ̀ mẹ́ rin láti mú àyípadà ọ̀ tún àti ṣíṣe àkóso ìṣèjọba tó dúró ire
Loading...
Date
Journal Title
Journal ISSN
Volume Title
Publisher
Abstract
AI kìí ṣe ọ̀ nà àbùjá láti ṣe àtúntò ìjọba. Láì sí àlàkalẹ̀ ìlànà ìṣàmúlò fún àtúntò, ohun èlò tó pójú owó àti ìlànà ìṣèjọba tó yé yéké, ṣíṣe àmúlò AI, ó ṣeé ṣe kí ìṣàmúlò rẹ̀ mú ìkúrẹtẹ̀ bá ètò ìṣejọba àti àìsí ìbòjútó pọ̀ si ju kí ó mú ìgbéga bá tàbí ṣíṣe tàbí òdodo lọ
Àṣeyọrí AI nínú ìjọba jẹ́ ìpèníjà fún ìṣèjọba kìí ṣe ti ìmọ̀ ẹ̀ rọ. Àwọn àbájáde kò gbáralé bí ìmọ̀ ẹ̀ rọ ṣe lágbára tó dípò bí àwọn ilé iṣẹ́ ṣe lágbára sí, àwọn ìlànà ìṣàfihàn, agbára àjọṣepọ̀ àwọn olùtajà, àti ìlànà ìfaradà.
A ṣe àgbékalẹ̀ ìgbésẹ̀ mẹ́ rin: ṣíṣe àtúntò àwọn ohun tí aráàlú ń lò lórí àwọn ìṣòro rẹ̀ gangan ṣáájú ṣíṣe àgbákalẹ̀ AI; ṣíṣe ìdókoòwò sí ṣíṣe ìdánilẹ́ kọ̀ ọ́ fáwọn òṣìṣẹ́ ní gbogbo ẹ̀ ka, ṣàgbéyẹ̀ wò agbára àwọn olùtajà láti ri pé àjọṣepọ̀ wà nípasẹ̀ ríra ọjà lápapọ̀ àti ìlò AI èyí tí aráàlú jẹ́ aṣojú rẹ̀ lábẹ́ àkóso kan èyí tí wọ́ n gbé kalẹ̀ lórí ìṣàfihàn tòótọ́ àti àbójútó tó péye.
* Original document in English: https://doi.org/10.20381/s959-yx05
Description
Keywords
artificial intelligence, government, public sector
